Lil Kesh – Abija Wara Lyrics

Abija Wara Lyrics By Lil Kesh

Abija Wara Lyrics
Abija Wara Lyrics
  • Artist Lil Kesh
  • Title Abija Wara
  • Album Yagi

(Pheelz Mr. Producer)
Rather be king in the streets than be a slave in the city
Tẹ ba lọ copycat ẹ le last, yara be quickie
Tẹ ba lọ gbemu debi, lẹbẹ la ma fi ge bọlẹ
Emi n fo, iwọ naa n fo, ki lo foṣi le bọlẹ (Eh)
Abija wara one, Abija, Abija wara one, gbera
Dagunro wa at alert, Dagunro, Dagunro wa at alert, gbera
Abija wara one, Abija, Abija wara one, gbera
Dagunro wa at alert, Dagunro, Dagunro wa at alert, gbera
Ibilẹ, you know that we keeping it real ko sẹni wọ yansh pad nibi
Jọ ba mi le awọn atọọle yii lọle ko sẹni wọ pampers nibi
Ṣe mo ba ẹ fẹyin abi ṣe mo smile ko sẹni lo Wi-Fi nibi
Ti n ba fun ẹ ni five fingers iya ẹ niyẹn, no high five nibi
Ma wo awọn babies
Wọn kan n wo bi ẹni to ti ko rabies
Mo ma ti gbogbo wọn mọnu cages
Have been doing this s***t for like ages, s***t for like ages
Emi ijaya
O dẹ mọ pe mo duro mo gallant
Small boy with a voice of a giant
Ma lọ jẹ ki Dagunro mi para, Dagunro mi para
Kesh
Mr. Mi Yagi
Rather be king in the streets than be a slave in the city
Tẹ ba lọ copycat ẹ le last, yara be quickie
Tẹ ba lọ gbemu debi, lẹbẹ la ma fi ge bọlẹ
Emi n fo, iwọ naa n fo, ki lo foṣi le bọlẹ (Eh)
Abija wara one, Abija, Abija wara one, gbera
Dagunro wa at alert, Dagunro, Dagunro wa at alert, gbera
Abija wara one, Abija, Abija wara one, gbera
Dagunro wa at alert, Dagunro, Dagunro wa at alert, gbera
Dagunro wa at alert
Abija wọ Rayban o tun wọ hat
Asiko mi re lati lowo bi egbere ja Royal Rumble and take their mat
Oponu o ti ẹ smart
Oloorun go and take your bath
B.Q lo n gbe, o lowo flat
Ṣo ya were abo jasi?
O fẹ gba visa Christ Embassy
Ẹni mọwe ṣa lo pass eemọ re ara adugbo ẹ ba mi dasi
Obago, Keshi pẹlu Chinko lori track yii
Kẹ to gbọ set, go ẹ ma gbọ on your marki
Run, run for your life
Run, run
Kasa, Tiger
Rather be king in the streets than be a slave in the city
Tẹ ba lọ copycat ẹ le last, yara be quickie
Tẹ ba lọ gbemu debi, lẹbẹ la ma fi ge bọlẹ
Emi n fo, iwọ naa n fo, ki lo foṣi le bọlẹ (Eh)
Abija wara one, Abija, Abija wara one, gbera
Dagunro wa at alert, Dagunro, Dagunro wa at alert, gbera
Abija wara one, Abija, Abija wara one, gbera
Dagunro wa at alert, Dagunro, Dagunro wa at alert, gbera
Ọọ mụ ka ha na-emele agidi
Ha amaho na flow mụ dị acidic
Ha nechalụ m anya sị na adị m lazy, mụ
Fuck it, I’m going back to basics
You and your crew
Amaa n-fit-nwukwe na my shoe
Akpa chaa m anya we gosi ha the clue
So how come these boys are so confused
Hold up, ha e-move-go, ha ka kwụkwa na hold up nụ
Neezienụ shows anyị kụgazi now, fa ncha bụkwa sold out-nụ
This MC don hammer wow all these haters they can’t touch-nụ
Ịchọta my squad egosị gị ụdị osimili that you can’t cross-nụ
You can’t cross-nu
Nwanne, you can’t cross-nu
Squad deep like the blue sea, it’s obvious that you can’t cross-nu

READ ALSO  Davido – Tell Everybody (feat. Leon Thomas) Lyrics

Leave A Comment