Bella Shmurda – Apala Fusion Lyrics

Apala Fusion Lyrics By Bella Shmurda

Apala Fusion Lyrics
Apala Fusion Lyrics

(We no be Baba Sálá)
(Ẹ pè wá l’ọmọ Haruna Ishola)
(Ònilu mi á lu’lu, á dun gbi-gbim gbi-gbim)
(We no be motor t’òbá dun pim-pim-pim)
(Ẹ jẹ á j’áyè yi, no shaking)
(Áriwò kọ ni music)
(Yo Dibs)
(Ẹni bá lè jò, kò má-má mi kọ)
(Ilu wá ò lè, álujò wá ò lè)
(Kò má-má mi kọ)
(Ilu wá ò lè, álujò wá ò lè)
I keep it hundred
I no like f’áyáwọ, I no like f’áyágbè, wọn bẹh
Ehn, I no dey take nonsense
I just like to dey shame, I just like to dey go, who stress me? I’m stressed
I’m getting everything wey I desire
All of my pain ni mò fi s’árá
I no far from God, ni mò ṣe n dárá
If I call you G, you be my brother (aya)
Òri mi, má jẹn m’òṣi
Ẹlẹdá mi, má jẹn t’òṣi
My pikin no go far from money
Eko no be London, my G
Òyá, f’áyá gbè, f’áyá kò
Ṣè kin pọn mi si, ṣè kin dá mi si (ayaya, ya-ya-ya)
Òyá, go, bẹrẹ kò (kò-kò)
Bámi pọn mi si, ṣè kin dá mi si
Mò yá bẹrẹ kò, bẹrẹ kò, ayy
(Má gbá mi, má rò mi kiri)
Say, I no be wanted, hundred
I keep it hundred
Busybody, ẹ jẹkin j’áyè
Busybody, ẹ jẹkin s’áyè miò
Ọmọtena jọọr, make I s’áyè
Ọmọtena jọọr, make I s’áyè miò, oh-oh
Kò ṣ’ẹni tò l’ẹmi mèji (ayy-ayy)
T’èmi yè mi (oh-oh), I’m not lazy (ayy-ah, Ogunlesi)
Ah, kò s’Ọlọhun mèji (kò s’Ọlọhun mèji)
The ọtá many, pẹlu agency
I keep it hundred
I no like f’áyáwọ, I no like f’áyágbè, wọn bẹh
(Ayy, Bella pass Shmurda)
Ehn, I no dey take nonsense (locate)
I just like to dey shame, I just like to dey go, wan stress, ṣ’on bẹh (wanted, many lie)
I’m getting everything wey I desire
All of my pain ni mò fi s’árá
I no far from God, ni mò ṣe n dárá
If I call you G, you be my brother
Òri mi, má jẹn m’òṣi
Ẹlẹdá mi, má jẹn t’òṣi
My pikin no go far from money
Eko no be London, my G
Òyá, f’áyá gbè (my G, Eko no be London, my G)
(We no be Baba Sálá)
(Ẹ pè wá l’ọmọ Haruna Ishola)
(Ònilu mi á lu’lu, á dun gbi-gbim gbi-gbim)
(We no be motor t’òbá dun pim-pim-pim)
(Ẹ jẹ á j’áyè yi, no shaking)
(Áriwò kọ ni music)
(Ẹni bá lè jò, kò má-má mi kọ)
(Ilu wá ò lè, álujò wá ò lè)
(Kò má-má mi kọ)
(Ilu wá ò lè, álujò wá ò lè)

READ ALSO  Naira Marley – Happy Lyrics (feat. Mayorkun)

Leave A Comment