Tag: Illiterate

  • Oladips & BhadBoi OML – Chaos Lyrics (feat. Illiterate)

    Óbèlè wèlùwè
    Illiterate
    (Maximus, Maximus), Óbèlè wè’
    Ọmọ Égbá dè (The Disciples Music)
    Óbèlè wè, é shèè’mí
    Óbèlè wè, wè-wè
    Ọlabode l’òrukó mi, òriki mi l’Adisa
    Wọn mó mi n’ilé álawó dùdù n’dèdè Africa
    Ambition mi tobi gan, ambition mi rópótó
    Kin ma b’áwọn èyinbò jeun ninu ábọ wọn yọkótó
    B’obá s’eyinbo si mi, èmi na á dè soh Yor’ba
    Kinwá j’óba l’èwọn l’óri, t’éni t’ọma soh d’ọgá
    B’èyankan bà bèh si mi, k’oló bàmi ju sinu tüübù
    Ẹni t’óba bà yásò pà, iru èyàn bè, kó kin sun mù
    Illiterate ni min l’òòtó, iwè timò ká, ò por
    Sugbón mò mó Maths, mò mó addition, mò mó áròpó
    Ẹlè r’òmi l’òjùmi, t’òri-emi ò bàwón r’árokàn
    Ti bámi ò ba lowò máalu, má yá bàwón pá aguntàn
    Ẹmi yátó s’àwọn kàn, tóh ma’n fake perfection
    Wọn bà mà jin si kòtò, kàlò take direction
    È s’èni yò mò tàn, è s’èni mistake ò lè bà
    Nkàn t’ọmówè bà gbá, Illiterate ò lè gba
    Moti shèè tan, é gbè mi
    Òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
    Ẹ ma fi’na gbè mi
    Òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
    Ah, I don’t lie, I’ll jéébi
    Áráyin n’ekiló fun, áráyin n’ekiló fun
    Áráyin n’ekiló fun
    Ọmu yágo o kin s’ọre ẹnikan, ọmọyin n’ekiló fun
    Angel Gabriel in heaven, Angel Gabriel in heaven
    Moti shèè tan, é gbè mi
    Òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
    Ẹ ma fi’na gbè mi
    Òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
    Ẹmi l’Ọtolorin, number one, è dè si counterfeit
    Ishèè élèyi yátò, ishèè èlèyí l’on pè ni masterpiece
    B’imba fẹ to l’oru, èmi nikàn ni mó man dá piss
    So, málo photo-bomb selfie mi, ah tinbá shà pics
    Shout-out s’áwọn t’èmi l’Égba, mò mó pè oriyin mà swell
    At’awọn t’ómá gb’orin mi, t’òma bèèrè sini ma twerk
    Awọn ọmọmi Kafila, awọn ọmọmi Baliki
    Awọn ọmọ t’ojèpe, gbogbo abẹ wọn ni mo s’aami si
    Gbẹgede gbinà, Egedè fẹ yèwò (yèwò)
    Ẹjenfisiyin l’ẹgbéwò wò
    Wọnjo pè wa si show l’ójósi, sugbón é l’ána, èmi ni sisi yin dè fẹwo (fẹwo)
    L’ẹwa d’eni tó k’eshèè bo (‘shèè bo)
    Tioba s’ẹba, lojẹ semo
    Ko sháá ti gba kadara lo shèè koko
    Mà pada si ésé aaro, má pada si’zero
    Ah, wọn ni pè mo high b’ẹni pè moti fa cannabis
    Èmi tun ni rapper ton kó lyrics pélu Arabic
    “Game Changer” l’ónpé mi, leader of the new school
    Awọn agba gan timo reason t’awọn o dè fini sùn, ah
    Moti shèè tan, é gbè mi
    Òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
    Ẹ ma fi’na gbè mi
    Òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
    Ah, I don’t lie, I’ll jéébi
    Áráyin n’ekiló fun, áráyin n’ekiló fun
    Áráyin n’ekiló fun
    Ọmu yágo o kin s’ọre ẹnikan, ọmọyin n’ekiló fun
    Angel Gabriel in heaven, Angel Gabriel in heaven
    Moti shèè tan, é gbè mi
    Òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
    Ẹ ma fi’na gbè mi
    Òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
    Óbèlè wèlùwè, óbèlè wèè