Qdot – Is a Gaju Lyrics Snippet (feat. IYA SOLO)

Is a Gaju Snippet Lyrics By Qdot

Is a Gaju Snippet Lyrics
Is a Gaju Snippet Lyrics

Is a Gaju
Mo gbe ori wole (Is a Gaju)
Mo mo awon temi (Is a Gaju)
Awon temi moni (Is a Gaju)
Bawo lose fesi? (Is a Gaju)
Orukomi ti po gan (Is a Gaju)
Won pe mi ni aroko feyin (Is a Gaju)
Won pe mi ni randu gbo’ko (Is a Gaju)
Motun n je were olomo (Is a Gaju)
J.S 3 ni mo wa (Is a Gaju)
Ki olohun mafi pamilekun (Is a Gaju)
Nkan je Solomon (Is a Gaju)
Ikeji n je Esther (Is a Gaju)
Eleketa n je Michael (Is a Gaju)
Omo ti mogbe ni (Is a Gaju)
Mo tu fi oko baba e se mic (Is a Gaju)
Ti mofi n korin nii eidi (Is a Gaju)
Tailor to n dorikodo (Is a Gaju)
Walahi o mo oun to’nran (Is a Gaju)
Awon omo mi almanjiri (Is a Gaju)
Rhyto.com

READ ALSO  BhadBoi OML – Alimanjiri (Remix) Lyrics [feat. Qdot]

Leave A Comment