March 24 II Lyrics By Oladips

Aw!
Omo Iya Aje
(The Disciples Music)
Ahan-ahan
Okay!
March 24
March 24
Tó ń bá gbọ́ lyrics mi, níṣin Olóhun wọ́n máa fọ̀!
March 24
March 24
Tó ń bá gbọ́ bars tí mo ń spit, Olóhun…
(12 Years Later!!!)
So mo wà ní airport ní Murtala, mo ń lọ Southy
Ọ̀ṣà ló ṣe visa, kí passport tó di pantí
Shout out sí padimi Mr Hadio Olaoye
Ìwà àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ní airport ń wù kọjá olè
Ọ̀tọ̀ l’áwọn tó máa bá ẹ tí bá ẹ pẹ̀lú trolley
Tó bá di next time, o máa ti fún wọn ní kọ́yìn
Ọ̀tọ̀ l’áwọn NDLEA tó máa search luggage
Owó ló ń fẹ́ gba, olè gbé coco pẹ̀lú courage
Àgàgà tó bá popular, wà rí àwọn tó máa hail ẹ
“Are you a musician or footballer? Abi gay ni ẹ?”
Àwọn ìbéèrè àpòda tó máa end pẹ̀lú billing
Ọ̀tọ̀ l’áwọn tó wọ uniform àti àwọn tó wọ guinea
Mo ti rí counter mi, mo wà lórí queue, tí mo ti check-in
Ẹni tó bá mí tí bag mọ́ sọ́fún pé mo máa ṣe 10k
“Call your account, bank wo ni?” – ó ní Opay
“You go see alert,” mo ti tẹ sí ẹ bí Èjì-Ogbè
Lórí queue ni mo wà tí mo ti bẹ̀rẹ̀ pé
“Ṣé mo ní yellow card?”
Mo rò pé visa nikan ni mo need
Tó bá ti jẹ́ local?
South Africa ni ilé náà, neighboring country
Ìbẹ̀ ló ti jẹ́ kí n mọ̀ pé I never see
Mo ṣàrà card yẹn, wọ́n bá mi fill ẹ
Mo san bí 20k
Ìbẹ̀ ni mo ti ń rò inú ilé mi
Bóyá mo rántí kpa
Bóyá mo pa TV
Bóyá mo pa AC àti fridge
Bóyá mo ti ilékùn ilé
Ọpọlọ ti ń yọ̀rọ̀ ní 36
Nígbà tí mo ń lọ, mo ti wà níwájú counter
“Good afternoon sir, good afternoon ma”
Mo answer
“Can I have your passport and all your itinerary?”
February 11th
Ó dà bíi pé ṣì January
She checked my visa, ticket — legit
Passport mi ni proof pé mo exist
My backpack is heavy, na hin me I still dey struggle with
She said:
“How many luggages & bags are you traveling with?”
I get 2 heavy luggages
With one other backpack
Economy queue — kò sí nkan tó jẹ fast track
Mo fi bags sí machine
Check-in, wọ́n weigh-in
Wọ́n fún mi ní boarding pass
Now I’m on my way in
Mo ti ń lọ through barricade
Mo ń find gate
Rollercoaster
It feels like I’m on a blind date
Then I met immigration
Àwọn náà tún bí mi question
Same style, same format
Blame it on recession
Dem don dey piss me off already
I was angry
Most of the people working at the airport
Are hungry
Mo fẹ́ kan travel
Make I find my gate with no stressing
Double wahala for you
If you are a known person
Mo ti rí gate
Mo jókòó ní terminal
Mo rí àwọn kan tó gather
Bí seminar
Before boarding
Àwọn ènìyàn ń wo
Nigeria vs Côte d’Ivoire (Final)
Nigeria 2–1
Ara wa dé tì báalẹ̀
Announcement!!!
FlySAA passengers are now boarding
Lagos to O.R Tambo — we dey jam body
So mo wà nínú plane
Seat mi wà lẹ́gbẹ̀ window
Mo ń rò mummy mi
Woman yẹn ṣẹ̀ṣẹ̀ di widow
2023 February 12 — my papa die
1 year later, I’m crying on a plane
“Chicken or beef?”
Observation is the best thing
No matter what you dey go through
My brother, first eat
Mo gba rice
Pẹ̀lú sauce àti chicken
Ṣé inú store ni? Abi kitchen?
Dem no sabi cook
Wetin I chop no dey taste well
30,000 feet above sea level
Altitude
Air-hostess fún mi attitude
Anyways
Mo gbé headphone sí etí
Mo ń wo movie
6 hours flight
Good weather
We were moving
Good plane
Good pilot
No turbulence
FlySAA — luxury, opulence
5:00am — we land for Joburg
Call Scofield
“Bro, you dey come?”
Ó ní:
“Mo ń duro de ẹ l’íta”
Immigration for SA
Wọ́n ní issue pẹ̀lú e-visa
“Excuse me sir!”
“My name is Oladips
I’m an artiste from 9ja”
Wọ́n ní kí n wá sí office
For questioning
Interview left and right
With tension
“What are you here for?”
“Touring or visiting?”
Mo show receipts
Hotel reservation
They wan verify
But hotel no pick
Problem start
“One chance only — we no fit call again”
Next thing
Wọ́n carry me go detention
Phone gone
Passport gone
Cell life
24 hours
I no fit reach my people
Scofield dey worry
Zlatan, Leczy — dem dey try
2 days later
Dem return my phone
Update:
“Dem go deport you in 4 days”
4 days later
Back to 9ja
But Scofield no gree
Him buy new ticket
5 days later
Back to SA again
This time — success
I enter
I see Scofield outside airport
Bentley
Security
Tinted
If you get real ones
Keep them
Outro:
Happy birthday to me
Illiterate Omo Ègbá Dé
Omo Ègbá Dé
Omo Ègbá Dé
Flows tí mo gbé dé
Ọ̀nyọ bread, òde ń yo butter
Best rappers yin
Ti gba ẹ̀kúnlẹ̀ — wọ́n yó bóta
I’ve been in the shadows
Mo ń dún mọ́huru
But mi ò rap
Arghh!