Brymo – Ààrẹ Lyrics

Ààrẹ Lyrics By Brymo

Ààrẹ Lyrics
Ààrẹ Lyrics

Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si, ó máa ta pàò-pàò
Ọlọpá wá o, ó máa gba rìbá
Òrékelẹwà jẹ a ṣeré
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
Ọlọpá wá o, ó máa gba rìbá
Òrékelẹwà, jẹ a ṣeré
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò
Ẹku owurọ o (ọlọpá wá o)
Ìròyìn láti ìgboro la mú wá kàn yín létí
Wọn ní, “Ní òwúrọ yìí, àwọn ọmọ éèès!
Wọn ti jà wọ’gboro
Wọn dẹ ti ń dáná sun’lé
Wọn tun dáná s’oko
Àt’ọkọ ayọkẹlẹ àti èyí tí ò yọkẹlẹ
Gbogbo ẹ lo dáná sun”
Ẹ gbélé yín o
Ẹ ṣọ’ra yín o
Ẹ pe àwọn ọmọ yín sọdọ
Èyí tí ò bá lọ sílé ìwé, kó jókòó
Kí Ọlọrun kí ó máa ṣọ gbogbo wa o
Láyọ o, ẹ ṣe e
Ààrẹ ń bọ l’ájò
Àwọn ọ mọ’wé takùn sọ’rùn l’áàfin
Àwọn ọjẹ’lú dúró ṣigidi ọkọ òfurufú
Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi
Orí mi ló gbé mi k’ore
Ààrẹ ń bọ l’ájò
Àwọn ọ mọ’wé takùn sọ’rùn l’áàfin
Àwọn ọjẹ’lú dúró ṣigidi ọkọ òfurufú
Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi
Orí mi ló gbé mi k’ore

READ ALSO  Rexxie, taves & Minz – IF I DIDN'T KNOW Lyrics

Leave A Comment