2:30 Lyrics By Asake

Obah!
Run
Ololade mi Asake
Awa de, awa de de
Awa lọmọ to n sọ ti o seke, ye
Orimọlade gbe mi de’bẹ
Jigan Jigan, ẹsẹ mi o de’lẹ, de’lẹ
Alaye mi stop ṣe bẹẹ
O fẹ jẹ n’bi, o tun fẹ jẹ n’bẹ, o pọ sẹ
Agbawo, fẹnu fo fence
Sun sẹyin
A mọra wa, ṣo get?
Abinibi yatọ s’ability
Ẹ sọ fun wọn t’ọn ba tẹri si
Wọn maa palori
Tẹnu kọ, emi promising
Awọn tẹ fọ fun n fọ fun mi
Tori ko s’ẹlomi
Many, many fẹ da bi mi, ẹ ẹ ri bi
Ẹ gb’Ọlọrun tobi
Mo da aṣọ-ẹbi for my country
You can call me Mr Money
Hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹ lu
O ya ka turn up ki ilẹ to mọ
Hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm (Ye, ye, ye)
2:30 fẹ lu (’30 fẹ lu)
O ya ka turn up ki ilẹ to mọ
Ere mo ba wa ko si ija
Ṣokoto penpe, ye, aye ni’ka, yebo, yeba
Formation lo gba, ye ja
Ọmọ’yami ko stay wise
Tranquility, tranquility
I no get time to dey form activity
Ko le kalas, I dey find stability
Like Abacha, money long infinity
What’s the chances? What’s the probability?
To see a better version of me with agility
No you can’t fake reality
Ogun, principality and calamity
Mo ti lọ, mo ti pa iyẹn ti
Bẹbẹ no dey for Jiji
O ṣi wa n titi
Still get money like 50
Dripping like Fiji
I be real G
Hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹ lu
O ya ka turn up ki ilẹ to mọ
Hmm, hmm, hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹ lu
O ya ka turn up ki ilẹ to mọ