Awodi Lyrics By Asake

Awodi fo loke o fẹ d’Oluwa
Ẹ ri bi, ẹ ri bi, I wonder
Wonder shall never end, like Pasuma I wonder
I wonder, American wonder, whoa
Ki ni reason, ki ni plan, ki ni scope, why the beefing?
Catfish lori titi, jẹ ẹ bi chicken, ṣọbọlọyọke ju billing
Iwaju gan-an easy, ẹyin o ṣe lọ, ọmọ iya mi ṣo ti ri nsi?
My ship never sinking, mo kanaku mo jiggy
They wanna know what I’m thinking
Many, many things I no fit ṣalaye
2022 mo ge wọn trabaye, oh
Oluwa lo ge, from the slum to the top
Emi kọ, awọn kọ wọn o le t’Ọlọrun
Iṣu jọba lori iyan kẹnimaani jọba oṣika
Ojo lọkọ agbado as e de go jasi, my ****
Aroma jogẹ, aroma le wọn, aroma de ‘bẹ fa ‘bẹ ya, oh
Mo ge wọn bi Babayaro, akabikaola o ya ka’bi lori awa, oh
Awodi fo loke o fẹ d’Oluwa
Ẹ ri bi, ẹ ri bi, I wonder
Wonder shall never end, like Pasuma I wonder
I wonder, American wonder, whoa
Ki ni reason, ki ni plan, ki ni scope, why the beefing?
Catfish lori titi, jẹ ẹ bi chicken, ṣọbọlọyọke ju billing
Iwaju gan-an easy, ẹyin o ṣe lọ, ọmọ iya mi ṣo ti ri nsi?
My ship never sinking, mo kanaku mo jiggy
They wanna know what I’m thinking
They wanna know
They wanna know
Aroma jogẹ, aroma le wọn, aroma de ‘bẹ fa ‘bẹ ya, oh
Mo ge wọn bi Babayaro, akabikaola o ya ka’bi lori awa, oh