Brymo – Adédọ̀tun Lyrics

Adédọ̀tun Lyrics By Brymo

Adédọ̀tun Lyrics
Adédọ̀tun Lyrics
  • Artist Brymo
  • Title Adédọ̀tun
  • Album Yellow

Awọn adan n fo loke
Wọn fọnka soju ọrun
Wọn o ma mọbi wọn n lọ
Eledua lo n ṣekẹ wọn
Ko kẹyin si ẹ, ọrẹ o
Ohun ọ n wa
O wa niwaju rẹ o
Adedọtun
Oyindamọla mi
Ero gbogbo ẹ ba n gberin
Adedọtun o
Awọn adan n fo loke
Nigba igba wọn kun oju ọrun
Wọn o ma mọ ihun wọn n jẹ
Eledua lo n ṣọ wọn, lo n bọ wọn
Ko pamọ si ẹ
Ọrẹ ooooooo
O wa lọ Sokoto
O wa lapo ṣokoto
Adedọtun
Oyindamọla mi
Ero gbogbo ẹ ba n gberin
Adedọtun o
Adedọtun
O-Oyindamọla mi
Ero gbogbo ẹ ba n gberin
Adedọtun o
Ko pamọ si ẹ
Ọrẹ ooooooo
Ohun ọ n wa
O wa niwaju rẹ ooooooo

READ ALSO  Brymo – Gambu Lyrics

Leave A Comment