DJ Tunez & Terry Apala – Apala Groove Lyrics

Apala Groove Lyrics By DJ Tunez

Apala Groove Lyrics
Apala Groove Lyrics
  • Artist DJ Tunez
  • Featured Terry Apala
  • Title Apala Groove
  • Album Apala Groove – Single

Mukulu mukẹkẹ
Sọdi to ba fẹ tẹ
Anti Rukẹwẹ
Ka mukulu mukẹkẹ
Mukulu mukẹkẹ
Sọdi to ba fẹ tẹ
Anti Rukẹwẹ
Ka mukulu mukẹkẹ
Ṣo gbọ mi ni?
Ọlọhun ma jẹ n toṣi, ma jẹ n ṣ’oriburuku
Life sweet me, ka ma parole, ka ma jẹun lọ
Ọlọhun ma jẹ n jiya, ma jẹ n ṣakobata f’ẹgbẹ mi
Life sweet, ka ma gbadun, ka ma flenjor
Wọn mu Coke, emi mu beer
No be ṣere kan bia
Ẹyin temi ẹ boode
Ọti pọ ninu garawa
Ṣana si cigar fun mi ki n bẹna lọ
Awọn ọmọge wọn pọ lẹyin mi, ṣo gbọ mi ni?
Ọti pọ ninu garawa
Wọn wa mi dele, wọn ọ ba mi nile
Ọjọ Friday ka lọ ṣere
Orin apala la tun gbe de
Ṣo gbọ mi ni?
Takasufe la fẹ kẹ jo si
Put on your dancing shoe, agbada pẹlu danṣiki
Ẹ kijo mọlẹ, ṣo gbọ? Hip hop hurray
Tonight is the night, ma jẹ ko d’ọla, lọ mura
Iro and buba, I go put on my agbada, ka ma gbadun lọ
Wọn mu Coke, emi mu beer
No be ṣere kan bia
Ẹyin temi ẹ boode
Ọti pọ ninu garawa
Ṣana si cigar fun mi ki n bẹna lọ
Awọn ọmọge wọn pọ lẹyin mi, ṣo gbọ mi ni?
Ọti pọ ninu garawa
Wọn mu Coke, emi mu beer
No be ṣere kan bia
Ẹyin temi ẹ boode
Ọti pọ ninu garawa
Ṣana si cigar fun mi ki n bẹna lọ
Awọn ọmọge wọn pọ lẹyin mi, ṣo gbọ mi ni?
Ọti pọ ninu garawa
Mukulu mukẹkẹ
Sọdi to ba fẹ tẹ
Anti Rukẹwẹ
Ka mukulu mukẹkẹ
Mukulu mukẹkẹ
Sọdi to ba fẹ tẹ
Anti Rukẹwẹ
Ka mukulu mukẹkẹ
Tonight is the night, ma jẹ ko d’ọla, lọ mura
Iro and buba, I go put on my agbada, ka ma gbadun lọ

READ ALSO  BNXN – Mukulu Lyrics

Leave A Comment