FOLA – attention! Lyrics

attention! Lyrics By FOLA

attention! Lyrics
attention! Lyrics
  • Artist FOLA
  • Title attention!
  • Album Single

You just want to chill oh
But problem will find you come in, for where the chilling spot

Holiday, holiday mon ami
K’owó mi dé, hm, màá kọkọ lé e wọn dànù
Oh, who dey roll the J?
Tó bá ti we’kàn, bá n mu
Èkó ilé, ask my nigga, ẹmélòó mò ń calcu’

Ẹrù tí mo kack, orí na disturbance
T’oke, ti’lẹ mi Balenciaga
Gettin’ money, gettin’ paid, pẹlú ìkánra
Young Money, Cash Money dey, Barry, rọra
O lèe wọ panpa mi, ọmọ yìí, rọra

Look am (e be like she do jazz, àbí ẹ o rí)
Calm down (Aminatu, calm down, ìbàdí rẹ’)
Ó gaa (ó ń gbé mi dé’bẹẹ’)
Àb’o rí dollar? (I go buy you latest)

Lifestyle ni ko ni gara
Owo dey, mi o bother
‘Cause her bum bum big, she need pamper
Call me Daddy Yo when I soco
Mo gbe o loju wọn, ko ma ṣakitibọbọ
(Baby o) ẹ ma wo combination, motion
O ti gba attention mi

O ti gba attention mi
That’s my pension ni
Nkan ti mo wọ ni pe
Iwọ lo ma gba pension mi
Bi’mọ fun mi, extension mi
Cure pressure yii with one, one Mary Jane
Join me, ka jọ gba lecture yii

Ẹrù tí mo kack, orí na disturbance
T’oke, ti’lẹ mi Balenciaga
Gettin’ money, gettin’ paid, pẹlú ìkánra
Young Money, Cash Money dey, Barry, rọra
O lèe wọ panpa mi, ọmọ yìí, rọra

Look am (e be like she do jazz, àbí ẹ o rí)
Calm down (Aminatu, calm down, ìbàdí rẹ’)
Ó gaa (ó ń gbé mi dé’bẹẹ’)
Àb’o rí dollar? (I go buy you latest)

READ ALSO  FOLA – who does that? Lyrics (feat. Bella Shmurda)

Lifestyle ni ko ni gara
Owo dey, mi o bother
‘Cause her bum bum big, she need pamper
Call me Daddy Yo when I soco
Mo gbe o loju wọn, ko ma ṣakitibọbọ
(Baby o) ẹ ma wo combination, motion
O ti gba attention mi

Leave A Comment