Eledumare Lyrics By Teledalase

Edumare jẹ n rayọ fi ṣaye
Onibu-ọrẹ j’ayọ ba mi kalẹ
Ma gbayọ lọwọ mi Eledumare
Ma jẹ n fikoro ṣe ile-aye
Ma, ma, ma, ma gbayọ lọwọ mi Eledua o
Ma jẹ n fikoro ṣaye
Kayọ mi pọ, kayọ mi pọ dalẹ
Ẹbẹ ni mo bẹ o
Ani kayọ mi pọ, kayọ mi pọ dalẹ
Ẹbẹ ni mo bẹ o
Oh, Eledumare, Eledumare
Ma gbayọ lọwọ mi
Eledumare, Eledumare
Ma, ma ṣe gbọmọ lọwọ mi
Da mi si, da mi si
Fayọ yẹ mi
Da mi si oh, da mi si oh
Fayọ yẹ mi, fayọ yẹ mi
Eledumare, Eledumare oh
Eledumare
Ma gbọmọ lọwọ mi
Fayọ kunu mi, fayọ kunu mi, fayọ kunu mi
J’ayọ ba mi dalẹ
Eledumare
Ma gbayọ lọwọ mi
Eledumare, abiamọ ti n gbọmọ rẹ lọfin gbohun mi
Baba gbohun mi
Eledumare, Eledumare
Fayọ kunu mi, fayọ kunu mi
Ma gbayọ lọwọ mi
Eledumare
Fayọ kunu mi
Eledumare, Eledumare