Teejay’s WRLD – GHETTO DISCO (feat. DJ Yk Mule) Lyrics

GHETTO DISCO Lyrics By Teejay’s WRLD

GHETTO DISCO Lyrics
GHETTO DISCO Lyrics
  • Artist Teejay’s WRLD
  • Featured DJ Yk Mule
  • Title GHETTO DISCO
  • Album GHETTO DISCO (feat. DJ Yk Mule) – Single

Cana yẹn, o wọna
Tori ti bombay mi o fẹ jọ, mi o gbọ nnkan kan mọ
Aye n lọ ninu uptown
T'ọmọ owo ti di drug baron
O ṣa mọ wọn ni fẹ bẹ
Ẹni to ba ẹ, o ti gented
Mopol ninu Mushin
Kọkọ ṣeba fun awọn ọmọ Kesari
DJ spirit, ogo Mushin
Ṣọki Atila the life of the party
Owo ni mo fẹ, mi o fẹ wahala o
Ki Maga ti maa dawo sinu PayPal
Ọmọ London wa a gbayi
**** to n ṣe **** lanfani
Swagun mo gallant
Emi lọmọ ti gbogbo obinrin n ja si
Mi o fẹ ma sin balance
PAiD, Easy Cash, Waseh Lavish
Ti Nako ba gbori wọle, a ma sare
Tapo ba dẹnu lẹ ọmọ ọmọ ọpẹ ma mu'je
LUXURY, Timmy XTREAM
Shay Gas wọle pẹlu Don Julio
Dandan nii k'awa naa gbori wọ Europe
Hunter Boys ninu Mushin
Slushy o sunmọ skushiz
Iba fun awọn ọmọ Orita Buyer
Sunderland wọn ki i ma wa wahala
To ba bẹ o ma jẹ ẹ
To ba ki i gbọrọ, o ma tẹ
Sabo Cross say 'Boko'
Ọmọ Mushin say 'Mopol'
Shibinshi ko da rara
Hustle lo n jawo mi, wey my dealer?
I know say I be sinner
RIP Khalypsoo ọmọ Ina
Wọn mọ iru ti ẹ D'Way
Garby Lanshy fun mi lakunu shey
Alarẹmu mi CEO
Wo, da Bacadin yẹn sinu H20
Ọmọ were wa ṣo ti ku ri
Sniper yẹn ṣo ti mu ri
Ase o ti tranga
Ifa ọmọ ọpẹ o ti fa a ja
Ah, bakki lo like ko ma ṣa
Colo lo fa to fi sa l'Aro
Wọn ba, wọn jẹ
Ko fẹ were, owo lo fẹ
Ike lo n tẹ
Ṣẹ r'aye yii a jọ ma jẹ
Pawo ma payan
Baba kan lo pa ra ẹ to tun salọ
No salary Ajikawo
Wọn n pe ẹ ni FELA, o dẹ ki n fagbo
Oscroh lohun o ki i ṣe parol
Ki wa lo fẹ ṣẹlẹ lẹyin igba ti mo ti tẹwo
O sọnu lapa ibi
O bajẹ o tun wa n ṣagidi

READ ALSO  Mr Eazi – Feelings Lyrics

Leave A Comment