Je'nwi Temi (Don't Gag Me) Lyrics By Fela Kuti

Hey, ehn, hey, oh, eh
Ti n ba r'ootọ ma sọ o, o le pa'nu mi de o
Ehn, oh
Jẹ n wi temi o, o le pa'nu mi de o
Ehn, oh, oh
Maa la'nu bi apẹre o, o le pa'nu mi de o, ehn
Ke, ke-ke, ke-ke, hey
Ke-ke, ke-ke, hey
Ke-ke, ke-ke, hey
Ke-ke, ke-ke, hey
E dede du-de o
E dede du-de o
Ti n ba r'ootọ ma sọ o
O le pa'nu mi de o, ma gbọ
Jẹ n wi temi o, jẹ n wi temi o
O le pa'nu mi de o, ehn
Otitọ koro
O le pa'nu mi de o, rara, Ọlọhun
E dede du-de, ehn
E dede du-de, ehn-ehn, ehn
E dede du-de o
Ke-ke, ke-ke, ke-ke, hey
Oh, oh, ehn, oh, ke-ke, oh
Bo ti mi mọ'le o, o le pa'nu mi de o, ehn-ehn
Maa la'nu bi apẹrẹ o, o le pa'nu mi de o, ehn
Ke-ke, ke-ke, ehn
Ke-ke, ke-ke, ehn
Ke-ke, ke-ke, hey!
E dede du-de eh
Ti n ba r'ootọ ma sọ o
O le p'enu mi de o
Padlock mi o si l'ọwọ ẹ o
Akandagodo mi o si l'ọwọ ẹ o
O le pa'nu mi de o, ehn
E dede du-de eh
E dede du-de
E dede du-de
Ti n ba r'ootọ ma sọ o
O le pa'nu mi de o, ehn
Ti n ba r'ootọ ma sọ o
O le pa'nu mi de o, ehn
Padlock mi o si l'ọwọ ẹ o
O le pa'nu mi de o
Akandagodo mi o si l'ọwọ ẹ o
O le pa'nu mi de o, ehn
Bo ti mi mọ'le o, o le pa'nu mi de o, ehn-ehn
Ma gbọ, ma gbọ bi baba wa ṣe n wi
Ma gbọ bi baba wa ṣe n sọ, ma gbọ, gbọ
Maa gbọ bi baba wa ṣe n wi
Ma gbọ bi baba wa ṣe n sọ, ma gbọ, gbọ, ma gbọ, ma gbọ
Jẹ nwi temi, sẹ o (jẹ nwi temi)
Ehn, jẹ nwi temi o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
Ehn, otitọ koro, ọmọ araye o fẹ o
Otitọ koro, ọmọ araye o fẹ o
Bẹẹfẹ, bẹẹfẹ o, eh, emi a wi temi o
Bẹẹfẹ, bẹẹfẹ o, eh, emi a wi temi o
Jẹ nwi temi, sẹ o (jẹ nwi temi)
Ehn, jẹ nwi temi o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
O le pa'nu de (o le pa'nu de)
O le pa'nu de (o le pa'nu de)
O le pa'nu de (o le pa'nu de)
O le pa'nu de (o le pa'nu de)
(O le pa'nu de)
(O le pa'nu de)
(O le pa'nu de)
Hey, oh
Ehn, ma gbọ
Ehn, hey, hey
Jẹ nwi temi, sẹ o (jẹ nwi temi)
Ehn, jẹ nwi temi o o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
Otitọ koro, ọmọ araye o fẹ o
Otitọ koro o, ọmọ araye o fẹ o
Bẹẹfẹ, bẹẹfẹ o, eh, emi a wi temi
Bẹẹfẹ, bẹẹfẹ o, eh, emi a wi temi o
Jẹ nwi temi, sẹ o (jẹ nwi temi)
Jẹ nwi temi o o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
Òwò kii f'òwò l'ọrun o (jẹ nwi temi)
O le pa'nu de (o le pa'nu de)
O le pa'nu de (o le pa'nu de)
(O le pa'nu de)
Bo ti mi mọ'le o (o le pa'nu de)
Padlock mi o si l'ọwọ ẹ o (o le pa'nu de)
Maa la'nu bi apẹrẹ o (o le pa'nu de)
(O le pa'nu de)
(O le pa'nu de)
Apado dede du-de
E dede du-de
E dede du-de
O le pa'nu de
O le pa'nu de