BBO – My God Lyrics

My God Lyrics By BBO

My God Lyrics
My God Lyrics
  • Artist BBO
  • Title My God
  • Album My God – Single

Oh oh, oh oh, oh oh
Ọlọrun mi, ọkọ mi ih Baba mi o, ọkọ mi titi lai
Ọlọrun awọn ọmọ ogun
Iwọ l'Ọlọrun mi
Ọlọrun mi
Iwọ l'Ọlọrun mi, Iwọ l'Ọlọrun mi
Ọlọrun mi
Ṣe o ma sọrọ, ko o lo kojẹ? No no, nooo
Ngbọ ṣe o ma sọrọ, ko sọ pe iwọ ko lo sọ Ọlọrun majẹmu? Rara o
You will be my strength when I am weak, my God (My God) My God
You will be my joy when I am sad, my God (My God)
Iwọ a ma jẹ agbara fun mi nigba to be fẹ rẹ mi o, ọkọ mi
Wa maa jẹ okun fun mi nigba to ba fẹ su mi, sir
You will be my strength when I am weak my God (My God)
You will be my strength
You will be my strength when I am weak, my God
Ọlọrun majẹmu jẹ agbara mi, tori nigba miran o ma fẹ su mi
Fi ayọ re kun inu emi Boluwatife ati awọn to n gbọ mi, o dẹ jẹ imolẹ mi
Ọmọ imọlẹ ni mi, okunkun o ni bori mi laye
You'll stand by me, (You'll stand by me as a pillar of cloud by day, my God)
Iji ayé lè fi mi lakalaka bi ki n padà lẹyin rẹ, ọkọ mi ṣugbọn rara o
Challenges life yìí o, o to ohun to n mu ẹda dakẹ iyin rẹ, Ọlọrun mi
Amọ gbogbo ohun tí a bá n dọjuko ni ile-aye
Ka ṣa gbagbọ ninu ọrọ Ọlọrun ọba
Tori o le mai ti ma jọ o
Ọlọrun mi o le parọ
O lè mai ti ma fojú jọ sẹ
Ko kọkọ jọ nígbà tó sọ pé Sarah máa bímọ (O dẹ pada bimọ)
Ko jo nígbà tí ó sọ pé Josẹfu máa doke o
Sẹbi Ọlọrun mi o le parọ
A ṣe Dafidi darandaran ṣi maa pada jọba
Ọlọrun mi, ẹ ki i ṣonirọ
And Isaac sowed in the land, in that same year he reaped a hundred fold
Gbogbo ẹda to n sunkun ileri ọjọ to ti pe, to da bi igba pe ọjọ ti n lọ pe o ti n pẹ ju o
Ẹyin wọnyi ẹ gbọ, a ran mi si yin o, wò mí o, wò mí o, wò mí o, ọrẹ mi
Ìwọ tó ti su yìí, ìwọ ni mò n bá wí
B'ẹkun pẹ dalẹ kan, ayọ n bọ lowurọ niwe mimọ wi
Ẹni ipa pin fun, dìde ko gba agbára o o, rántí pé ọrọ Oluwa ko ni lọ láì ṣẹ́
Ileri ọjọ tipẹ n bọ wa si imuṣẹ o
Ọlọrun o ki n ṣe ọmọ ènìyàn tó ń parọ o
A o lè bá irọ lẹnu yin ọmọ Ọlọrun, ah ah
Ẹ o ki n parọ o

READ ALSO  EmmaOMG – Jesu Daddy Mi (feat. Mabel Omajuwa, BBO, Nosa & The OhEmGee Choir) Lyrics

Leave A Comment