Ọkán Mi Ti Fọ́ Wẹ́wẹ́ Lyrics By Brymo

Iyawo kan mi n pa mi lọ geere
Wọn l’olufoya ni mi, oh oh
Ọkunrin to le fẹ mẹta, mẹrin ah ah
Pe mo sa, mo sa, ẹru de mi mọlẹ
Ọkan mi ti fọ wẹwẹ
Ọkan mi ti pin yẹlẹyẹlẹ
Nigba miiran nifẹ fẹ ma wu
Lati ibi ẹwa kọrọ ẹmi mi
Ko tun ni wu
Mo mọ o ṣe buruku
O file lẹ tipẹtipẹ
Ma yọ apa mi fun ọ
O lo n ba ẹ ‘nu jẹ
Binu mi n dun
Ko dara
Ọkan mi ti fọ wẹwẹ
Ọkan mi ti pin yẹlẹyẹlẹ
Nigba miiran nifẹ fẹ ma wu
Lati ibi ẹwa kọrọ ẹmi mi
Ko tun ni wu