Niniola – Too Sweet (O Dun) Lyrics

Too Sweet (O Dun) Lyrics By Niniola

Too Sweet (O Dun) Lyrics
Too Sweet (O Dun) Lyrics
  • Artist Niniola
  • Title Too Sweet (O Dun)
  • Album Lagos to Jozi – EP

Nini de
Ọmọ yẹn pọ
Akowọnjọ (Ko wọn jọ)
You fit take am for holiday, she heavy gan-an
Working every night and day to buy mansion (Mansion)
Ṣẹkẹrẹ de (Yeah)
Ṣẹkẹrẹ de
Ṣẹkẹrẹ ma ju
Ọmọ yẹn dun (O dun, o dun)
Ọmọ yẹn sweet (Sweet, o sweet o sweet)
Ọmọ yẹn ladun
Ọmọ yẹn nice
Owo lo pa (Owo lo pa)
I know I’m nice
T’ọmọ yẹn lọrun
Give her what she likes
Ọmọ larọ larọ kutu Monday morning
Ọmọkọmọ pelu OG with the money
Ọmọ larọ, larọ kutu Monday morning
Ọmọkọmọ pọju lori, lori agbo
Tiri titi (Da da da da)
Tiri titi (Da da da da)
Kaarọ o jiire, hmmm, kale (Kale, kale, kale)
Tiri titi
Tiri tititi
How long can you tọju me for?
My head touch my toes
Just think about it
Ṣo le tọju mi to?
Now and forever more
Ọmọ yẹn dun (O dun, o dun)
Ọmọ yẹn sweet
Ọmọ yẹn dun dun
Ọmọ yẹn nice
Owo lo pa (Owo lo pa)
I know I’m nice
T’ọmọ yẹn lọrun
Give her what she likes
Ọmọ larọ, larọ kutu Monday morning (Monday morning)
Ọmọkọmọ pẹlu OG with the money
Ọmọ larọ, larọ kutu Monday morning
Ọmọkọmọ pọju lori, lori agbo
Ọmọ yẹn dun
Ọmọ yẹn sweet (Sweet, o sweet, o sweet)
Ọmọ yẹn ladun
Ọmọ yẹn nice
Owo lo pa (Owo lo pa)
I know I’m nice

READ ALSO  Niniola – Omo Rapala Lyrics

Leave A Comment