Brymo – Alelúyà Méje Lyrics

Alelúyà Méje Lyrics By Brymo

Alelúyà Méje Lyrics
Alelúyà Méje Lyrics
  • Artist Brymo
  • Title Alelúyà Méje
  • Album 9: Èsan

Alelúyà méje-méje
Òṣèlú péjọ fọjọ méje
Wọn fẹ tolú lọjọ méje
Gbogbo iṣẹlẹ kanrinkese
Alelúyà méje-méje
Àwọn ojẹlu ferege
Wọn lawọn ọmọ-yepa tún ti dé
Wọn fẹ dalúrú, merele
Alelúyà méje-méje
Akonilẹ́rú wọn tún ti dé
Wọn fẹ sọ bo ṣe ma ma gbé
Iwọ fokun sọrun o n ṣiṣẹ agbe
Gbogbo iṣẹlẹ kanrinkese
Wọn lawọn omidan lo n maye le
Wọn fẹ jẹka, wọn fẹ roṣọ
Oko lo n maye ọkùnrin le
Bo kọ iwájú sí ẹ ko ta
Bo ba kẹyin si ẹ ko ta
Bo ba ku iwọ nikan ṣe ohun o lè ṣe
Ma gbàgbé ibi o ti ń ba bọ
Bo kọ iwájú sí ẹ ko ta
Bo ba kẹyin si ẹ ko ta
Bo ba ku iwọ nikan ṣe ohun o lè ṣe
Ma gbàgbé ibi o ti ń ba bọ
Alelúyà méje-méje (A-re-pe paropa)
Adalérú wọn tún ti de (A-re-pe paropa)
Kò fẹ kọmọ o mọ baba rẹ (A-re-pe paropa)
Kò fẹ kọkọ o gbọ taya rẹ (A-re-pe paropa)
Gbogbo iṣẹlẹ kanrinkese (A-re-pe paropa)
Wọn lawọn omidan lo n máyé le (A-re-pe paropa)
Wọn fẹ jẹka, wọn fẹ roṣọ (A-re-pe paropa)
Oko ló n maye ọkùnrin le (A-re-pe paropa)
Eh-ya, yah, ya

READ ALSO  Brymo – Òṣìkà Lyrics

Leave A Comment