Brymo – Fura Sára Lyrics

Fura Sára Lyrics By Brymo

Fura Sára Lyrics
Fura Sára Lyrics
  • Artist Brymo
  • Title Fura Sára
  • Album 9: Èsan

O pa mi lẹkun
O wa fun mi lakara jẹ
Mo sunkun, mo gboju
O ni n sare lọ sọja
Bo wun mi n bugijẹ
Ah ah ah ah ah ah ah
Olo mi dakun jọwọ oh
Dakun jọwọ oh
Ye gbọ tẹlẹgan
Ye gbọ tẹlẹgan
Ye gbọ tẹlẹgan
Fura si wọn
O gbaja onija ja
O n ja fara ‘ta
Bo ba ya wa danu gbaga
Wa a lemi ni mo ṣaida
Ah ah ah ah ah ah ah
Obinrin yii dakun jọwọ oh
Dakun jọwọ oh
Ye gbọ tẹlẹgan
Ye gbọ tẹlẹgan
Ye gbọ tẹlẹgan
Fura si ara

READ ALSO  Falz – Wazup Guy Lyrics

Leave A Comment